Eyin Jesu Oluwa,
Wa sinu okan mi.
Dari ese mi ji mi.
We mi si we mi.
So mi di ominira.
Jesu, O seun pe O ku fun mi.
Mo gbagbo pe O jinde kuro ninu oku.
Ati pe O tun pada wa fun mi.
Fi Emi Mimo kun mi.
Fun mi ni itara fun awọn ti o sọnu.
Ebi fun awon nkan Olorun.
Ati igboya mimọ lati waasu Ihinrere Jesu Kristi.
A ti gbà mí là!
A ti bí mi ní àtúnbí!
A ti dárí jì mí!
Mo si n lo si Orun.
Nitori mo ni Jesu ninu okan mi.
